Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shams ayat 8 - الشَّمس - Page - Juz 30
﴿فَأَلۡهَمَهَا فُجُورَهَا وَتَقۡوَىٰهَا ﴾
[الشَّمس: 8]
﴿فألهمها فجورها وتقواها﴾ [الشَّمس: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sì fi ẹ̀ṣẹ̀ (tí ẹ̀mí lè dá) àti ìbẹ̀rù rẹ̀ mọ̀ ọ́n |