Quran with Yoruba translation - Surah Al-Lail ayat 11 - اللَّيل - Page - Juz 30
﴿وَمَا يُغۡنِي عَنۡهُ مَالُهُۥٓ إِذَا تَرَدَّىٰٓ ﴾
[اللَّيل: 11]
﴿وما يغني عنه ماله إذا تردى﴾ [اللَّيل: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dúkìá rẹ̀ kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ nígbà tí ó bá já bọ́ (sínú Iná) |