Quran with Yoruba translation - Surah At-Tin ayat 6 - التِّين - Page - Juz 30
﴿إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَعَمِلُواْ ٱلصَّٰلِحَٰتِ فَلَهُمۡ أَجۡرٌ غَيۡرُ مَمۡنُونٖ ﴾
[التِّين: 6]
﴿إلا الذين آمنوا وعملوا الصالحات فلهم أجر غير ممنون﴾ [التِّين: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àyàfi àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n sì ṣe àwọn iṣẹ́ rere. Nítorí náà, ẹ̀san tí kò níí pin (tí kò níí pẹ̀dín) ń bẹ fún wọn |