Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Alaq ayat 15 - العَلَق - Page - Juz 30
﴿كـَلَّا لَئِن لَّمۡ يَنتَهِ لَنَسۡفَعَۢا بِٱلنَّاصِيَةِ ﴾
[العَلَق: 15]
﴿كلا لئن لم ينته لنسفعا بالناصية﴾ [العَلَق: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Bẹ́ẹ̀ ni (Allāhu ń rí i.) Dájúdájú tí kò bá jáwọ́ (níbi dídí i lọ́wọ́), dájúdájú A máa fi àásó orí rẹ̀ wọ́ ọ (sínú Iná) |