Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qadr ayat 5 - القَدر - Page - Juz 30
﴿سَلَٰمٌ هِيَ حَتَّىٰ مَطۡلَعِ ٱلۡفَجۡرِ ﴾
[القَدر: 5]
﴿سلام هي حتى مطلع الفجر﴾ [القَدر: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àlàáfíà ni òru náà títí di àsìkò àfẹ̀mọ́júmọ́ |