Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qadr ayat 4 - القَدر - Page - Juz 30
﴿تَنَزَّلُ ٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ وَٱلرُّوحُ فِيهَا بِإِذۡنِ رَبِّهِم مِّن كُلِّ أَمۡرٖ ﴾
[القَدر: 4]
﴿تنـزل الملائكة والروح فيها بإذن ربهم من كل أمر﴾ [القَدر: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn mọlāika àti Jibrīl yó sì máa sọ̀kalẹ̀ nínú òru náà pẹ̀lú àṣẹ Olúwa wọn fún gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan |