Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 105 - يُونس - Page - Juz 11
﴿وَأَنۡ أَقِمۡ وَجۡهَكَ لِلدِّينِ حَنِيفٗا وَلَا تَكُونَنَّ مِنَ ٱلۡمُشۡرِكِينَ ﴾
[يُونس: 105]
﴿وأن أقم وجهك للدين حنيفا ولا تكونن من المشركين﴾ [يُونس: 105]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Wọ́n tún pa mí láṣẹ pé): “Dojú rẹ kọ ẹ̀sìn náà, (kí o jẹ́) olùdúró-déédé-nínú-ẹ̀sìn. Ìwọ kò sì gbọdọ̀ wà nínú àwọn ọ̀ṣẹbọ |