Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 62 - يُونس - Page - Juz 11
﴿أَلَآ إِنَّ أَوۡلِيَآءَ ٱللَّهِ لَا خَوۡفٌ عَلَيۡهِمۡ وَلَا هُمۡ يَحۡزَنُونَ ﴾
[يُونس: 62]
﴿ألا إن أولياء الله لا خوف عليهم ولا هم يحزنون﴾ [يُونس: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Gbọ́, dájúdájú àwọn ọ̀rẹ́ Allāhu, kò níí sí ìbẹ̀rù (ìyà ọ̀run) fún wọn, wọn kò sì níí banújẹ́ (lórí oore ayé) |