Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 76 - يُونس - Page - Juz 11
﴿فَلَمَّا جَآءَهُمُ ٱلۡحَقُّ مِنۡ عِندِنَا قَالُوٓاْ إِنَّ هَٰذَا لَسِحۡرٞ مُّبِينٞ ﴾
[يُونس: 76]
﴿فلما جاءهم الحق من عندنا قالوا إن هذا لسحر مبين﴾ [يُونس: 76]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí òdodo dé bá wọn láti ọ̀dọ̀ Wa, wọ́n wí pé: “Dájúdájú èyí ni idán pọ́nńbélé.” |