Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 117 - هُود - Page - Juz 12
﴿وَمَا كَانَ رَبُّكَ لِيُهۡلِكَ ٱلۡقُرَىٰ بِظُلۡمٖ وَأَهۡلُهَا مُصۡلِحُونَ ﴾
[هُود: 117]
﴿وما كان ربك ليهلك القرى بظلم وأهلها مصلحون﴾ [هُود: 117]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Olúwa rẹ kò níí pa àwọn ìlú run lọ́nà àbòsí, nígbà tí àwọn ènìyàn rẹ̀ bá jẹ́ olùṣàtùn-únṣe |