Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 33 - هُود - Page - Juz 12
﴿قَالَ إِنَّمَا يَأۡتِيكُم بِهِ ٱللَّهُ إِن شَآءَ وَمَآ أَنتُم بِمُعۡجِزِينَ ﴾
[هُود: 33]
﴿قال إنما يأتيكم به الله إن شاء وما أنتم بمعجزين﴾ [هُود: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Nūh) sọ pé: "Allāhu l’Ó máa mú un wá ba yín tí Ó bá fẹ́. Ẹ̀yin kò sì níí mórí bọ́ |