Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 75 - هُود - Page - Juz 12
﴿إِنَّ إِبۡرَٰهِيمَ لَحَلِيمٌ أَوَّٰهٞ مُّنِيبٞ ﴾
[هُود: 75]
﴿إن إبراهيم لحليم أواه منيب﴾ [هُود: 75]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú (Ànábì) ’Ibrọ̄hīm ni aláfaradà, olùrawọ́rasẹ̀, olùronúpìwàdà |