Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 60 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿فَإِن لَّمۡ تَأۡتُونِي بِهِۦ فَلَا كَيۡلَ لَكُمۡ عِندِي وَلَا تَقۡرَبُونِ ﴾
[يُوسُف: 60]
﴿فإن لم تأتوني به فلا كيل لكم عندي ولا تقربون﴾ [يُوسُف: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ẹ ò bá sì mú un wá, kò sí (ẹrù oúnjẹ) wíwọ̀n fun yín lọ́dọ̀ mi. Kí ẹ sì má ṣe súnmọ́ mi |