Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 61 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالُواْ سَنُرَٰوِدُ عَنۡهُ أَبَاهُ وَإِنَّا لَفَٰعِلُونَ ﴾
[يُوسُف: 61]
﴿قالوا سنراود عنه أباه وإنا لفاعلون﴾ [يُوسُف: 61]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “A máa jírẹ̀ẹ́bẹ̀ fún un lọ́dọ̀ bàbá rẹ̀. Dájúdájú àwa máa ṣe bẹ́ẹ̀.” |