Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 89 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالَ هَلۡ عَلِمۡتُم مَّا فَعَلۡتُم بِيُوسُفَ وَأَخِيهِ إِذۡ أَنتُمۡ جَٰهِلُونَ ﴾
[يُوسُف: 89]
﴿قال هل علمتم ما فعلتم بيوسف وأخيه إذ أنتم جاهلون﴾ [يُوسُف: 89]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Ǹjẹ́ ẹ mọ ohun tí ẹ ṣe fún Yūsuf àti ọmọ-ìyá rẹ̀ nígbà tí ẹ̀yin jẹ́ aláìmọ̀kan.” |