Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 95 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالُواْ تَٱللَّهِ إِنَّكَ لَفِي ضَلَٰلِكَ ٱلۡقَدِيمِ ﴾
[يُوسُف: 95]
﴿قالوا تالله إنك لفي ضلالك القديم﴾ [يُوسُف: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “A fi Allāhu búra! Dájúdájú ìwọ sì wà nínú àṣìṣe rẹ ti àtijọ́ (nípa ìfẹ́ Yūsuf).” |