×

’Alif lam mim ro. Iwonyi ni awon ayah Tira naa. Ati pe 13:1 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:1) ayat 1 in Yoruba

13:1 Surah Ar-Ra‘d ayat 1 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 1 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿الٓمٓرۚ تِلۡكَ ءَايَٰتُ ٱلۡكِتَٰبِۗ وَٱلَّذِيٓ أُنزِلَ إِلَيۡكَ مِن رَّبِّكَ ٱلۡحَقُّ وَلَٰكِنَّ أَكۡثَرَ ٱلنَّاسِ لَا يُؤۡمِنُونَ ﴾
[الرَّعد: 1]

’Alif lam mim ro. Iwonyi ni awon ayah Tira naa. Ati pe ododo ni ohun ti won sokale fun o lati odo Oluwa re, sugbon opolopo awon eniyan ko gbagbo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: المر تلك آيات الكتاب والذي أنـزل إليك من ربك الحق ولكن أكثر, باللغة اليوربا

﴿المر تلك آيات الكتاب والذي أنـزل إليك من ربك الحق ولكن أكثر﴾ [الرَّعد: 1]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
’Alif lām mīm rọ̄. Ìwọ̀nyí ni àwọn āyah Tírà náà. Àti pé òdodo ni ohun tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ fún ọ láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ àwọn ènìyàn kò gbàgbọ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek