×

Inu awon Ogba Idera gbere ni won yoo wo, (awon) ati eni 13:23 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:23) ayat 23 in Yoruba

13:23 Surah Ar-Ra‘d ayat 23 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 23 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿جَنَّٰتُ عَدۡنٖ يَدۡخُلُونَهَا وَمَن صَلَحَ مِنۡ ءَابَآئِهِمۡ وَأَزۡوَٰجِهِمۡ وَذُرِّيَّٰتِهِمۡۖ وَٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ يَدۡخُلُونَ عَلَيۡهِم مِّن كُلِّ بَابٖ ﴾
[الرَّعد: 23]

Inu awon Ogba Idera gbere ni won yoo wo, (awon) ati eni t’o ba se rere ninu awon baba won, awon iyawo won ati awon aromodomo won. Awon molaika yo si maa wole to won lati enu ona kookan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: جنات عدن يدخلونها ومن صلح من آبائهم وأزواجهم وذرياتهم والملائكة يدخلون عليهم, باللغة اليوربا

﴿جنات عدن يدخلونها ومن صلح من آبائهم وأزواجهم وذرياتهم والملائكة يدخلون عليهم﴾ [الرَّعد: 23]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Inú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra gbére ni wọn yóò wọ̀, (àwọn) àti ẹni t’ó bá ṣe rere nínú àwọn bàbá wọn, àwọn ìyàwó wọn àti àwọn àrọ́mọdọ́mọ wọn. Àwọn mọlāika yó sì máa wọlé tọ̀ wọ́n láti ẹnu ọ̀nà kọ̀ọ̀kan
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek