×

(Awon ni) awon t’o se suuru lati fi wa Oju rere Oluwa 13:22 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:22) ayat 22 in Yoruba

13:22 Surah Ar-Ra‘d ayat 22 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 22 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿وَٱلَّذِينَ صَبَرُواْ ٱبۡتِغَآءَ وَجۡهِ رَبِّهِمۡ وَأَقَامُواْ ٱلصَّلَوٰةَ وَأَنفَقُواْ مِمَّا رَزَقۡنَٰهُمۡ سِرّٗا وَعَلَانِيَةٗ وَيَدۡرَءُونَ بِٱلۡحَسَنَةِ ٱلسَّيِّئَةَ أُوْلَٰٓئِكَ لَهُمۡ عُقۡبَى ٱلدَّارِ ﴾
[الرَّعد: 22]

(Awon ni) awon t’o se suuru lati fi wa Oju rere Oluwa won. Won n kirun. Won n na ninu ohun ti A pese fun won ni ikoko ati ni gbangba. Won si n fi rere ti aburu lo. Awon wonyen ni atubotan Ile rere n be fun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: والذين صبروا ابتغاء وجه ربهم وأقاموا الصلاة وأنفقوا مما رزقناهم سرا وعلانية, باللغة اليوربا

﴿والذين صبروا ابتغاء وجه ربهم وأقاموا الصلاة وأنفقوا مما رزقناهم سرا وعلانية﴾ [الرَّعد: 22]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Àwọn ni) àwọn t’ó ṣe sùúrù láti fi wá Ojú rere Olúwa wọn. Wọ́n ń kírun. Wọ́n ń ná nínú ohun tí A pèsè fún wọn ní ìkọ̀kọ̀ àti ní gban̄gba. Wọ́n sì ń fi rere ti aburú lọ. Àwọn wọ̀nyẹn ni àtubọ̀tán Ilé rere ń bẹ fún
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek