Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 24 - الرَّعد - Page - Juz 13
﴿سَلَٰمٌ عَلَيۡكُم بِمَا صَبَرۡتُمۡۚ فَنِعۡمَ عُقۡبَى ٱلدَّارِ ﴾
[الرَّعد: 24]
﴿سلام عليكم بما صبرتم فنعم عقبى الدار﴾ [الرَّعد: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Wọn yóò sọ pé): “Àlàáfíà fun yín nítorí ìfaradà yín.” Àtubọ̀tán Ilé náà sì dára |