×

Awon t’o n tu adehun Allahu leyin ti won ti gba adehun 13:25 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:25) ayat 25 in Yoruba

13:25 Surah Ar-Ra‘d ayat 25 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 25 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿وَٱلَّذِينَ يَنقُضُونَ عَهۡدَ ٱللَّهِ مِنۢ بَعۡدِ مِيثَٰقِهِۦ وَيَقۡطَعُونَ مَآ أَمَرَ ٱللَّهُ بِهِۦٓ أَن يُوصَلَ وَيُفۡسِدُونَ فِي ٱلۡأَرۡضِ أُوْلَٰٓئِكَ لَهُمُ ٱللَّعۡنَةُ وَلَهُمۡ سُوٓءُ ٱلدَّارِ ﴾
[الرَّعد: 25]

Awon t’o n tu adehun Allahu leyin ti won ti gba adehun Re, ti won n ja ohun ti Allahu pa lase pe ki won dapo, ti won si n se ibaje lori ile; awon wonyen ni egun wa fun. Ati pe Ile (Ina) buruku wa fun won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: والذين ينقضون عهد الله من بعد ميثاقه ويقطعون ما أمر الله به, باللغة اليوربا

﴿والذين ينقضون عهد الله من بعد ميثاقه ويقطعون ما أمر الله به﴾ [الرَّعد: 25]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn t’ó ń tú àdéhùn Allāhu lẹ́yìn tí wọ́n ti gba àdéhùn Rẹ̀, tí wọ́n ń já ohun tí Allāhu pa láṣẹ pé kí wọ́n dàpọ̀, tí wọ́n sì ń ṣe ìbàjẹ́ lórí ilẹ̀; àwọn wọ̀nyẹn ni ègún wà fún. Àti pé Ilé (Iná) burúkú wà fún wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek