×

Oun ni Eni ti O te ile perese. O si fi awon 13:3 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:3) ayat 3 in Yoruba

13:3 Surah Ar-Ra‘d ayat 3 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 3 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿وَهُوَ ٱلَّذِي مَدَّ ٱلۡأَرۡضَ وَجَعَلَ فِيهَا رَوَٰسِيَ وَأَنۡهَٰرٗاۖ وَمِن كُلِّ ٱلثَّمَرَٰتِ جَعَلَ فِيهَا زَوۡجَيۡنِ ٱثۡنَيۡنِۖ يُغۡشِي ٱلَّيۡلَ ٱلنَّهَارَۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَأٓيَٰتٖ لِّقَوۡمٖ يَتَفَكَّرُونَ ﴾
[الرَّعد: 3]

Oun ni Eni ti O te ile perese. O si fi awon apata t’o duro gbagidi sinu ile ati awon odo. Ati pe ninu gbogbo awon eso, O se e ni orisi meji-meji. O n fi oru bo osan loju. Dajudaju awon ami wa ninu iyen fun ijo t’o ni arojinle

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وهو الذي مد الأرض وجعل فيها رواسي وأنهارا ومن كل الثمرات جعل, باللغة اليوربا

﴿وهو الذي مد الأرض وجعل فيها رواسي وأنهارا ومن كل الثمرات جعل﴾ [الرَّعد: 3]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Òun ni Ẹni tí Ó tẹ́ ilẹ̀ pẹrẹsẹ. Ó sì fi àwọn àpáta t’ó dúró gbagidi sínú ilẹ̀ àti àwọn odò. Àti pé nínú gbogbo àwọn èso, Ó ṣe é ní oríṣi méjì-méjì. Ó ń fi òru bo ọ̀sán lójú. Dájúdájú àwọn àmì wà nínú ìyẹn fún ìjọ t’ó ní àròjinlẹ̀
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek