×

Dajudaju won ti fi awon Ojise kan se yeye siwaju re. Mo 13:32 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:32) ayat 32 in Yoruba

13:32 Surah Ar-Ra‘d ayat 32 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 32 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿وَلَقَدِ ٱسۡتُهۡزِئَ بِرُسُلٖ مِّن قَبۡلِكَ فَأَمۡلَيۡتُ لِلَّذِينَ كَفَرُواْ ثُمَّ أَخَذۡتُهُمۡۖ فَكَيۡفَ كَانَ عِقَابِ ﴾
[الرَّعد: 32]

Dajudaju won ti fi awon Ojise kan se yeye siwaju re. Mo si lo awon t’o sai gbagbo lara. Leyin naa, Mo gba won mu. Nitori naa, bawo ni iya (ti mo fi je won) ti ri (lara won na)

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولقد استهزئ برسل من قبلك فأمليت للذين كفروا ثم أخذتهم فكيف كان, باللغة اليوربا

﴿ولقد استهزئ برسل من قبلك فأمليت للذين كفروا ثم أخذتهم فكيف كان﴾ [الرَّعد: 32]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú wọn ti fi àwọn Òjíṣẹ́ kan ṣe yẹ̀yẹ́ ṣíwájú rẹ. Mo sì lọ́ àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ lára. Lẹ́yìn náà, Mo gbá wọn mú. Nítorí náà, báwo ni ìyà (tí mo fi jẹ wọ́n) ti rí (lára wọn ná)
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek