×

Nje Eni ti O n mojuto emi kookan nipa ise ti o 13:33 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ar-Ra‘d ⮕ (13:33) ayat 33 in Yoruba

13:33 Surah Ar-Ra‘d ayat 33 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Ra‘d ayat 33 - الرَّعد - Page - Juz 13

﴿أَفَمَنۡ هُوَ قَآئِمٌ عَلَىٰ كُلِّ نَفۡسِۭ بِمَا كَسَبَتۡۗ وَجَعَلُواْ لِلَّهِ شُرَكَآءَ قُلۡ سَمُّوهُمۡۚ أَمۡ تُنَبِّـُٔونَهُۥ بِمَا لَا يَعۡلَمُ فِي ٱلۡأَرۡضِ أَم بِظَٰهِرٖ مِّنَ ٱلۡقَوۡلِۗ بَلۡ زُيِّنَ لِلَّذِينَ كَفَرُواْ مَكۡرُهُمۡ وَصُدُّواْ عَنِ ٱلسَّبِيلِۗ وَمَن يُضۡلِلِ ٱللَّهُ فَمَا لَهُۥ مِنۡ هَادٖ ﴾
[الرَّعد: 33]

Nje Eni ti O n mojuto emi kookan nipa ise ti o se (da bi eni ti ko le se bee bi? Sibe) e tun ba Allahu wa awon akegbe kan! So pe: “E daruko won na.” Tabi eyin yoo fun (Allahu) ni iro ohun ti ko mo lori ile tabi (eyin yoo pa) iro funfun balau ni? Won kuku ti se ete ni oso fun awon t’o sai gbagbo. Won si seri won kuro loju ona ododo. Enikeni ti Allahu ba si lona, ko si nii si olutosona kan fun un

❮ Previous Next ❯

ترجمة: أفمن هو قائم على كل نفس بما كسبت وجعلوا لله شركاء قل, باللغة اليوربا

﴿أفمن هو قائم على كل نفس بما كسبت وجعلوا لله شركاء قل﴾ [الرَّعد: 33]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ǹjẹ́ Ẹni tí Ó ń mójútó ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan nípa iṣẹ́ tí ó ṣe (dà bí ẹni tí kò lè ṣe bẹ́ẹ̀ bí? Síbẹ̀) ẹ tún bá Allāhu wá àwọn akẹgbẹ́ kan! Sọ pé: “Ẹ dárúkọ wọn ná.” Tàbí ẹ̀yin yóò fún (Allāhu) ní ìró ohun tí kò mọ̀ lórí ilẹ̀ tàbí (ẹ̀yin yóò pa) irọ́ funfun báláú ni? Wọ́n kúkú ti ṣe ète ní ọ̀ṣọ́ fún àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́. Wọ́n sì ṣẹ́rí wọn kúrò lójú ọ̀nà òdodo. Ẹnikẹ́ni tí Allāhu bá ṣì lọ́nà, kò sì níí sí olùtọ́sọ́nà kan fún un
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek