×

Awon t’o sai gbagbo wi fun awon Ojise won pe: “Dajudaju awa 14:13 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Ibrahim ⮕ (14:13) ayat 13 in Yoruba

14:13 Surah Ibrahim ayat 13 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Ibrahim ayat 13 - إبراهِيم - Page - Juz 13

﴿وَقَالَ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ لِرُسُلِهِمۡ لَنُخۡرِجَنَّكُم مِّنۡ أَرۡضِنَآ أَوۡ لَتَعُودُنَّ فِي مِلَّتِنَاۖ فَأَوۡحَىٰٓ إِلَيۡهِمۡ رَبُّهُمۡ لَنُهۡلِكَنَّ ٱلظَّٰلِمِينَ ﴾
[إبراهِيم: 13]

Awon t’o sai gbagbo wi fun awon Ojise won pe: “Dajudaju awa yoo le yin jade kuro lori ile wa tabi ki e kuku pada sinu esin wa.” Nigba naa, Oluwa won fi imisi ranse si won pe: “Dajudaju A maa pa awon alabosi run

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وقال الذين كفروا لرسلهم لنخرجنكم من أرضنا أو لتعودن في ملتنا فأوحى, باللغة اليوربا

﴿وقال الذين كفروا لرسلهم لنخرجنكم من أرضنا أو لتعودن في ملتنا فأوحى﴾ [إبراهِيم: 13]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ wí fún àwọn Òjíṣẹ́ wọn pé: “Dájúdájú àwa yóò le yín jáde kúrò lórí ilẹ̀ wa tàbí kí ẹ kúkú padà sínú ẹ̀sìn wa.” Nígbà náà, Olúwa wọn fi ìmísí ránṣẹ́ sí wọn pé: “Dájúdájú A máa pa àwọn alábòsí run
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek