Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 13 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿لَا يُؤۡمِنُونَ بِهِۦ وَقَدۡ خَلَتۡ سُنَّةُ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[الحِجر: 13]
﴿لا يؤمنون به وقد خلت سنة الأولين﴾ [الحِجر: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò níí gba Ànábì (sollalāhu 'alayhi wa sallam) gbọ́; ìṣe (Allāhu lórí) àwọn ẹni àkọ́kọ́ kúkú ti ré kọjá |