Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 18 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿إِلَّا مَنِ ٱسۡتَرَقَ ٱلسَّمۡعَ فَأَتۡبَعَهُۥ شِهَابٞ مُّبِينٞ ﴾
[الحِجر: 18]
﴿إلا من استرق السمع فأتبعه شهاب مبين﴾ [الحِجر: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àfi (èṣù) tí ó bá jí ọ̀rọ̀ gbọ́. Nígbà náà sì ni ògúnná pọ́nńbélé yó tẹ̀lé e láti ẹ̀yìn |