Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 4 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَمَآ أَهۡلَكۡنَا مِن قَرۡيَةٍ إِلَّا وَلَهَا كِتَابٞ مَّعۡلُومٞ ﴾
[الحِجر: 4]
﴿وما أهلكنا من قرية إلا ولها كتاب معلوم﴾ [الحِجر: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò pa ìlú kan run rí àfi kí ó ní àkọsílẹ̀ tí A ti mọ̀ |