Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 79 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿فَٱنتَقَمۡنَا مِنۡهُمۡ وَإِنَّهُمَا لَبِإِمَامٖ مُّبِينٖ ﴾
[الحِجر: 79]
﴿فانتقمنا منهم وإنهما لبإمام مبين﴾ [الحِجر: 79]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì gbẹ́san lára wọn. Dájújájú àwọn ìlú méjèèjì l’ó kúkú wà lójú ọ̀nà gban̄gba (tí ẹ̀ ń tọ̀ lọ tọ̀ bọ̀) |