Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 23 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿لَا جَرَمَ أَنَّ ٱللَّهَ يَعۡلَمُ مَا يُسِرُّونَ وَمَا يُعۡلِنُونَۚ إِنَّهُۥ لَا يُحِبُّ ٱلۡمُسۡتَكۡبِرِينَ ﴾
[النَّحل: 23]
﴿لا جرم أن الله يعلم ما يسرون وما يعلنون إنه لا يحب﴾ [النَّحل: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò sí tàbí-ṣùgbọ́n, dájúdájú Allāhu mọ ohun tí wọ́n ń fi pamọ́ àti ohun tí wọ́n ń ṣe àfihàn rẹ̀. Àti pé dájúdájú (Allāhu) kò nífẹ̀ẹ́ àwọn onígbèéraga |