Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 24 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿وَإِذَا قِيلَ لَهُم مَّاذَآ أَنزَلَ رَبُّكُمۡ قَالُوٓاْ أَسَٰطِيرُ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[النَّحل: 24]
﴿وإذا قيل لهم ماذا أنـزل ربكم قالوا أساطير الأولين﴾ [النَّحل: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá sọ fún wọn pé: “Kí ni Olúwa yín sọ̀kalẹ̀? Wọ́n á wí pé: “Àkọsílẹ̀ àlọ́ àwọn ẹni àkọ́kọ́ ni.” |