Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 29 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿فَٱدۡخُلُوٓاْ أَبۡوَٰبَ جَهَنَّمَ خَٰلِدِينَ فِيهَاۖ فَلَبِئۡسَ مَثۡوَى ٱلۡمُتَكَبِّرِينَ ﴾
[النَّحل: 29]
﴿فادخلوا أبواب جهنم خالدين فيها فلبئس مثوى المتكبرين﴾ [النَّحل: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹ wọ àwọn ẹnu ọ̀nà Iná lọ, olùṣegbére ni yín nínú rẹ̀. Ibùgbé àwọn onígbèéraga sì burú |