Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 103 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿فَأَرَادَ أَن يَسۡتَفِزَّهُم مِّنَ ٱلۡأَرۡضِ فَأَغۡرَقۡنَٰهُ وَمَن مَّعَهُۥ جَمِيعٗا ﴾
[الإسرَاء: 103]
﴿فأراد أن يستفزهم من الأرض فأغرقناه ومن معه جميعا﴾ [الإسرَاء: 103]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, (Fir‘aon) fẹ́ kó wọn láyà jẹ lórí ilẹ̀. A sì tẹ òun àti àwọn t’ó wà pẹ̀lú rẹ̀ rì pátápátá |