Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 3 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿ذُرِّيَّةَ مَنۡ حَمَلۡنَا مَعَ نُوحٍۚ إِنَّهُۥ كَانَ عَبۡدٗا شَكُورٗا ﴾
[الإسرَاء: 3]
﴿ذرية من حملنا مع نوح إنه كان عبدا شكورا﴾ [الإسرَاء: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ẹ jẹ́) àrọ́mọdọ́mọ àwọn tí A gbé gun ọkọ̀ ojú-omi pẹ̀lú (Ànábì) Nūh. Dájúdájú (Nūh) jẹ́ ẹrúsìn, olùdúpẹ́ |