Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 37 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿وَلَا تَمۡشِ فِي ٱلۡأَرۡضِ مَرَحًاۖ إِنَّكَ لَن تَخۡرِقَ ٱلۡأَرۡضَ وَلَن تَبۡلُغَ ٱلۡجِبَالَ طُولٗا ﴾
[الإسرَاء: 37]
﴿ولا تمش في الأرض مرحا إنك لن تخرق الأرض ولن تبلغ الجبال﴾ [الإسرَاء: 37]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Má ṣe rìn lórí ilẹ̀ pẹ̀lú ìgbéraga; dájúdájú ìwọ kò lè dá ilẹ̀ lu, ìwọ kò sì lè ga tó àpáta |