Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 49 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿وَقَالُوٓاْ أَءِذَا كُنَّا عِظَٰمٗا وَرُفَٰتًا أَءِنَّا لَمَبۡعُوثُونَ خَلۡقٗا جَدِيدٗا ﴾
[الإسرَاء: 49]
﴿وقالوا أئذا كنا عظاما ورفاتا أئنا لمبعوثون خلقا جديدا﴾ [الإسرَاء: 49]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: “Ṣé nígbà tí a bá ti di egungun, tí a ti jẹrà, ṣé Wọ́n máa gbé wa dìde ní ẹ̀dá titun ni?” |