×

(Ranti) nigba ti A so fun awon molaika pe: "E fori kanle 17:61 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:61) ayat 61 in Yoruba

17:61 Surah Al-Isra’ ayat 61 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 61 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿وَإِذۡ قُلۡنَا لِلۡمَلَٰٓئِكَةِ ٱسۡجُدُواْ لِأٓدَمَ فَسَجَدُوٓاْ إِلَّآ إِبۡلِيسَ قَالَ ءَأَسۡجُدُ لِمَنۡ خَلَقۡتَ طِينٗا ﴾
[الإسرَاء: 61]

(Ranti) nigba ti A so fun awon molaika pe: "E fori kanle ki (Anabi) Adam." Won si fori kanle ki i afi ’Iblis. O wi pe: “Se ki ng fori kanle ki eni ti O fi amo seda re ni?”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وإذ قلنا للملائكة اسجدوا لآدم فسجدوا إلا إبليس قال أأسجد لمن خلقت, باللغة اليوربا

﴿وإذ قلنا للملائكة اسجدوا لآدم فسجدوا إلا إبليس قال أأسجد لمن خلقت﴾ [الإسرَاء: 61]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Rántí) nígbà tí A sọ fún àwọn mọlāika pé: "Ẹ forí kanlẹ̀ kí (Ànábì) Ādam." Wọ́n sì forí kanlẹ̀ kí i àfi ’Iblīs. Ó wí pé: “Ṣé kí n̄g forí kanlẹ̀ kí ẹni tí O fi amọ̀ ṣẹ̀dá rẹ̀ ni?”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek