Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 87 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿إِلَّا رَحۡمَةٗ مِّن رَّبِّكَۚ إِنَّ فَضۡلَهُۥ كَانَ عَلَيۡكَ كَبِيرٗا ﴾
[الإسرَاء: 87]
﴿إلا رحمة من ربك إن فضله كان عليك كبيرا﴾ [الإسرَاء: 87]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àyàfi ìkẹ́ láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ (ni kò fi ṣe bẹ́ẹ̀). Dájúdájú oore àjùlọ Rẹ̀ lórí rẹ tóbi |