Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 88 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿قُل لَّئِنِ ٱجۡتَمَعَتِ ٱلۡإِنسُ وَٱلۡجِنُّ عَلَىٰٓ أَن يَأۡتُواْ بِمِثۡلِ هَٰذَا ٱلۡقُرۡءَانِ لَا يَأۡتُونَ بِمِثۡلِهِۦ وَلَوۡ كَانَ بَعۡضُهُمۡ لِبَعۡضٖ ظَهِيرٗا ﴾
[الإسرَاء: 88]
﴿قل لئن اجتمعت الإنس والجن على أن يأتوا بمثل هذا القرآن لا﴾ [الإسرَاء: 88]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Dájúdájú tí àwọn ènìyàn àti àlùjànnú bá para pọ̀ láti mú irú al-Ƙur’ān yìí wá, wọn kò lè mú irú rẹ̀ wá, apá kan wọn ìbáà jẹ́ olùrànlọ́wọ́ fún apá kan |