Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 95 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿قُل لَّوۡ كَانَ فِي ٱلۡأَرۡضِ مَلَٰٓئِكَةٞ يَمۡشُونَ مُطۡمَئِنِّينَ لَنَزَّلۡنَا عَلَيۡهِم مِّنَ ٱلسَّمَآءِ مَلَكٗا رَّسُولٗا ﴾
[الإسرَاء: 95]
﴿قل لو كان في الأرض ملائكة يمشون مطمئنين لنـزلنا عليهم من السماء﴾ [الإسرَاء: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Tí ó bá jẹ́ pé àwọn mọlāika wà lórí ilẹ̀ ayé, tí wọ́n ń rìn kiri, (tí wọ́n ń gbé lórí ilẹ̀) pẹ̀lú ìfàyàbalẹ̀, A ìbá sọ mọlāika kan kalẹ̀ fún wọn láti inú sánmọ̀ (láti jẹ́) Òjíṣẹ́.” |