Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 103 - الكَهف - Page - Juz 16
﴿قُلۡ هَلۡ نُنَبِّئُكُم بِٱلۡأَخۡسَرِينَ أَعۡمَٰلًا ﴾
[الكَهف: 103]
﴿قل هل ننبئكم بالأخسرين أعمالا﴾ [الكَهف: 103]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Ṣé kí Á fun yín ní ìró àwọn ẹni òfò jùlọ nípa iṣẹ́ (ọwọ́ wọn) |