×

Awon ijo wa wonyi so awon kan di olohun leyin Allahu. Ki 18:15 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:15) ayat 15 in Yoruba

18:15 Surah Al-Kahf ayat 15 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 15 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿هَٰٓؤُلَآءِ قَوۡمُنَا ٱتَّخَذُواْ مِن دُونِهِۦٓ ءَالِهَةٗۖ لَّوۡلَا يَأۡتُونَ عَلَيۡهِم بِسُلۡطَٰنِۭ بَيِّنٖۖ فَمَنۡ أَظۡلَمُ مِمَّنِ ٱفۡتَرَىٰ عَلَى ٱللَّهِ كَذِبٗا ﴾
[الكَهف: 15]

Awon ijo wa wonyi so awon kan di olohun leyin Allahu. Ki ni ko je ki won mu eri t’o yanju wa nipa won? Nitori naa, ta ni o se abosi ju eni t’o da adapa iro mo Allahu

❮ Previous Next ❯

ترجمة: هؤلاء قومنا اتخذوا من دونه آلهة لولا يأتون عليهم بسلطان بين فمن, باللغة اليوربا

﴿هؤلاء قومنا اتخذوا من دونه آلهة لولا يأتون عليهم بسلطان بين فمن﴾ [الكَهف: 15]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn ìjọ wa wọ̀nyí sọ àwọn kan di ọlọ́hun lẹ́yìn Allāhu. Kí ni kò jẹ́ kí wọ́n mú ẹ̀rí t’ó yanjú wá nípa wọn? Nítorí náà, ta ni ó ṣe àbòsí ju ẹni t’ó dá àdápa irọ́ mọ́ Allāhu
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek