×

Awon wonyen, tiwon ni Ogba Idera gbere, ti awon odo yoo maa 18:31 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:31) ayat 31 in Yoruba

18:31 Surah Al-Kahf ayat 31 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 31 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿أُوْلَٰٓئِكَ لَهُمۡ جَنَّٰتُ عَدۡنٖ تَجۡرِي مِن تَحۡتِهِمُ ٱلۡأَنۡهَٰرُ يُحَلَّوۡنَ فِيهَا مِنۡ أَسَاوِرَ مِن ذَهَبٖ وَيَلۡبَسُونَ ثِيَابًا خُضۡرٗا مِّن سُندُسٖ وَإِسۡتَبۡرَقٖ مُّتَّكِـِٔينَ فِيهَا عَلَى ٱلۡأَرَآئِكِۚ نِعۡمَ ٱلثَّوَابُ وَحَسُنَتۡ مُرۡتَفَقٗا ﴾
[الكَهف: 31]

Awon wonyen, tiwon ni Ogba Idera gbere, ti awon odo yoo maa san ni isale won. Won yoo maa fi goolu orun se won ni oso ninu re. Won yoo maa wo aso aran alawo eweko (eyi ti o) fele ati (eyi ti) o nipon. Won yo si rogboku lori ibusun ola ninu (Ogba Idera). O dara ni esan. O si dara ni ibukojo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: أولئك لهم جنات عدن تجري من تحتهم الأنهار يحلون فيها من أساور, باللغة اليوربا

﴿أولئك لهم جنات عدن تجري من تحتهم الأنهار يحلون فيها من أساور﴾ [الكَهف: 31]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn wọ̀nyẹn, tiwọn ni Ọgbà Ìdẹ̀ra gbére, tí àwọn odò yóò máa ṣàn ní ìsàlẹ̀ wọn. Wọn yóò máa fi góòlù ọrùn ṣe wọ́n ní ọ̀ṣọ́ nínú rẹ̀. Wọn yóò máa wọ aṣọ àrán aláwọ̀ ewéko (èyí tí ó) fẹ́lẹ́ àti (èyí tí) ó nípọn. Wọn yó sì rọ̀gbọ̀kú lórí ibùsùn ọlá nínú (Ọgbà Ìdẹ̀ra). Ó dára ní ẹ̀san. Ó sì dára ní ibùkójọ
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek