×

Won si pa eso re run patapata. O si di eni t’o 18:42 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:42) ayat 42 in Yoruba

18:42 Surah Al-Kahf ayat 42 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 42 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿وَأُحِيطَ بِثَمَرِهِۦ فَأَصۡبَحَ يُقَلِّبُ كَفَّيۡهِ عَلَىٰ مَآ أَنفَقَ فِيهَا وَهِيَ خَاوِيَةٌ عَلَىٰ عُرُوشِهَا وَيَقُولُ يَٰلَيۡتَنِي لَمۡ أُشۡرِكۡ بِرَبِّيٓ أَحَدٗا ﴾
[الكَهف: 42]

Won si pa eso re run patapata. O si di eni t’o n fi owo re mejeeji lura won peepe nipa ohun ti o ti na sori re. O ti parun torule-torule re. O si n wi pe: “Yee! Emi iba ti so eni kan kan di akegbe fun Oluwa mi.”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وأحيط بثمره فأصبح يقلب كفيه على ما أنفق فيها وهي خاوية على, باللغة اليوربا

﴿وأحيط بثمره فأصبح يقلب كفيه على ما أنفق فيها وهي خاوية على﴾ [الكَهف: 42]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Wọ́n sì pa èso rẹ̀ run pátápátá. Ó sì di ẹni t’ó ń fí ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lura wọn pẹ́ẹ́pẹ́ nípa ohun tí ó ti ná sórí rẹ̀. Ó ti parun tòrùlé-tòrùlé rẹ̀. Ó sì ń wí pé: “Yéè! Èmi ìbá tí sọ ẹnì kan kan di akẹgbẹ́ fún Olúwa mi.”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek