Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 43 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿وَلَمۡ تَكُن لَّهُۥ فِئَةٞ يَنصُرُونَهُۥ مِن دُونِ ٱللَّهِ وَمَا كَانَ مُنتَصِرًا ﴾
[الكَهف: 43]
﴿ولم تكن له فئة ينصرونه من دون الله وما كان منتصرا﴾ [الكَهف: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Kò ní ìjọ kan tí ó máa ràn án lọ́wọ́ mọ́ lẹ́yìn Allāhu. Kò sì lè ran ara rẹ̀ lọ́wọ́ |