Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 54 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿وَلَقَدۡ صَرَّفۡنَا فِي هَٰذَا ٱلۡقُرۡءَانِ لِلنَّاسِ مِن كُلِّ مَثَلٖۚ وَكَانَ ٱلۡإِنسَٰنُ أَكۡثَرَ شَيۡءٖ جَدَلٗا ﴾
[الكَهف: 54]
﴿ولقد صرفنا في هذا القرآن للناس من كل مثل وكان الإنسان أكثر﴾ [الكَهف: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti ṣe àlàyé oníran-ànran sínú al-Ƙur’ān fún àwọn ènìyàn pẹ̀lú gbogbo àkàwé. Ènìyàn sì jẹ́ alátakò púpọ̀ ju ohunkóhun lọ |