×

Ko si ohun t’o di awon eniyan lowo lati gbagbo nigba ti 18:55 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:55) ayat 55 in Yoruba

18:55 Surah Al-Kahf ayat 55 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 55 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿وَمَا مَنَعَ ٱلنَّاسَ أَن يُؤۡمِنُوٓاْ إِذۡ جَآءَهُمُ ٱلۡهُدَىٰ وَيَسۡتَغۡفِرُواْ رَبَّهُمۡ إِلَّآ أَن تَأۡتِيَهُمۡ سُنَّةُ ٱلۡأَوَّلِينَ أَوۡ يَأۡتِيَهُمُ ٱلۡعَذَابُ قُبُلٗا ﴾
[الكَهف: 55]

Ko si ohun t’o di awon eniyan lowo lati gbagbo nigba ti imona de ba won, (ko si si ohun t’o di won lowo lati) toro aforijin Oluwa won, bi ko se pe (won fe) ki ise (Allahu nipa iparun) awon eni akoko de ba awon naa tabi ki iya de ba won ni ojukoju

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما منع الناس أن يؤمنوا إذ جاءهم الهدى ويستغفروا ربهم إلا أن, باللغة اليوربا

﴿وما منع الناس أن يؤمنوا إذ جاءهم الهدى ويستغفروا ربهم إلا أن﴾ [الكَهف: 55]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kò sí ohun t’ó dí àwọn ènìyàn lọ́wọ́ láti gbàgbọ́ nígbà tí ìmọ̀nà dé bá wọn, (kò sì sí ohun t’ó dí wọn lọ́wọ́ láti) tọrọ àforíjìn Olúwa wọn, bí kò ṣe pé (wọ́n fẹ́) kí ìṣe (Allāhu nípa ìparun) àwọn ẹni àkọ́kọ́ dé bá àwọn náà tàbí kí ìyà dé bá wọn ní ojúkojú
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek