Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 8 - الكَهف - Page - Juz 15
﴿وَإِنَّا لَجَٰعِلُونَ مَا عَلَيۡهَا صَعِيدٗا جُرُزًا ﴾
[الكَهف: 8]
﴿وإنا لجاعلون ما عليها صعيدا جرزا﴾ [الكَهف: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé dájúdájú Àwa máa sọ n̄ǹkan tí ń bẹ lórí (ilẹ̀) di erùpẹ̀ gbígbẹ tí kò níí hu irúgbìn |