Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 25 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَهُزِّيٓ إِلَيۡكِ بِجِذۡعِ ٱلنَّخۡلَةِ تُسَٰقِطۡ عَلَيۡكِ رُطَبٗا جَنِيّٗا ﴾
[مَريَم: 25]
﴿وهزي إليك بجذع النخلة تساقط عليك رطبا جنيا﴾ [مَريَم: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mi igi dàbínù náà sọ́dọ̀ rẹ, kí dàbínú tútù, tó tó ká jẹ sì máa jábọ́ sílẹ̀ fún ọ |