Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 29 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿فَأَشَارَتۡ إِلَيۡهِۖ قَالُواْ كَيۡفَ نُكَلِّمُ مَن كَانَ فِي ٱلۡمَهۡدِ صَبِيّٗا ﴾
[مَريَم: 29]
﴿فأشارت إليه قالوا كيف نكلم من كان في المهد صبيا﴾ [مَريَم: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sì tọ́ka sí ọmọ náà. Wọ́n sọ pé: “Báwo ni a ó ṣe bá ẹni t’ó wà lórí ìtẹ́, t’ó jẹ́ ọmọ òpóǹló sọ̀rọ̀?” |